Ìfihàn 16:1 BM

1 Mo gbọ́ ohùn líle kan láti inú Tẹmpili tí ó sọ fún àwọn angẹli meje náà pé, “Ẹ lọ da àwọn àwo meje tí ó kún fún ibinu Ọlọrun sinu ayé.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 16

Wo Ìfihàn 16:1 ni o tọ