Ìfihàn 16:10 BM

10 Angẹli karun-un da ohun tí ó wà ninu àwo rẹ̀ sórí ìtẹ́ ẹranko náà, ó bá sọ ìjọba rẹ̀ di òkùnkùn. Àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí gé ara wọn láhọ́n jẹ nítorí ìrora wọn,

Ka pipe ipin Ìfihàn 16

Wo Ìfihàn 16:10 ni o tọ