Ìfihàn 16:6 BM

6 Wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ àwọn eniyan rẹ ati àwọn wolii rẹ sílẹ̀, nítorí náà o fún wọn ní ẹ̀jẹ̀ mu. Ohun tí ó yẹ wọ́n ni o fún wọn!”

Ka pipe ipin Ìfihàn 16

Wo Ìfihàn 16:6 ni o tọ