Ìfihàn 17:10 BM

10 Marun-un ninu wọn ti kú. Ọ̀kan wà lórí oyè nisinsinyii. Ọ̀kan yòókù kò ì tíì jẹ. Nígbà tí ó bá jọba, àkókò díẹ̀ ni yóo ṣe lórí oyè.

Ka pipe ipin Ìfihàn 17

Wo Ìfihàn 17:10 ni o tọ