Ìfihàn 17:12 BM

12 “Àwọn ìwo mẹ́wàá tí o rí jẹ́ ọba mẹ́wàá. Ṣugbọn wọn kò ì tíì joyè. Wọn óo gba àṣẹ fún wakati kan, àwọn ati ẹranko náà ni yóo jọ lo àṣẹ náà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 17

Wo Ìfihàn 17:12 ni o tọ