Ìfihàn 17:17 BM

17 Nítorí Ọlọrun fi sí ọkàn wọn láti ní ète kan náà, pé àwọn yóo fi ìjọba àwọn fún ẹranko náà títí gbogbo ohun tí Ọlọrun ti sọ yóo fi ṣẹ.

Ka pipe ipin Ìfihàn 17

Wo Ìfihàn 17:17 ni o tọ