Ìfihàn 18:17 BM

17 Ní wakati kan péré ni gbogbo ọrọ̀ rẹ̀ run!”Nígbà náà ni gbogbo ọ̀gá àwọn awakọ̀ ojú omi, ati gbogbo àwọn tí ó ń wọ ọkọ̀ ati àwọn atukọ̀ ati àwọn tí iṣẹ́ wọn jẹ mọ́ ojú omi òkun lọ dúró ní òkèèrè.

Ka pipe ipin Ìfihàn 18

Wo Ìfihàn 18:17 ni o tọ