Ìfihàn 18:24 BM

24 Ninu rẹ ni a ti rí ẹ̀jẹ̀ àwọn wolii ati ẹ̀jẹ̀ àwọn eniyan Ọlọrun, ati gbogbo àwọn ẹni tí wọ́n pa lórí ilẹ̀ ayé.

Ka pipe ipin Ìfihàn 18

Wo Ìfihàn 18:24 ni o tọ