Ìfihàn 19:15 BM

15 Idà mímú yọ jáde ní ẹnu rẹ̀, tí yóo fi ṣẹgun àwọn orílẹ̀-èdè, nítorí òun ni yóo jọba lórí wọn pẹlu ọ̀pá irin. Òun ni yóo pọn ọtí ibinu ati ti ẹ̀san Ọlọrun Olodumare.

Ka pipe ipin Ìfihàn 19

Wo Ìfihàn 19:15 ni o tọ