Ìfihàn 19:21 BM

21 Wọ́n fi idà tí ó wà lẹ́nu ẹni tí ó gun ẹṣin funfun pa àwọn yòókù. Gbogbo àwọn ẹyẹ bá ń jẹ ẹran-ara wọn ní àjẹrankùn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 19

Wo Ìfihàn 19:21 ni o tọ