Ìfihàn 22:14 BM

14 Àwọn tí wọ́n bá fọ aṣọ wọn ṣe oríire. Wọn óo ní àṣẹ láti dé ibi igi ìyè, wọn óo sì gba ẹnu ọ̀nà wọ inú ìlú mímọ́ náà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 22

Wo Ìfihàn 22:14 ni o tọ