Ìfihàn 22:16 BM

16 “Èmi Jesu ni mo rán angẹli mi láti jíṣẹ́ gbogbo nǹkan wọnyi fún ẹ̀yin ìjọ. Èmi gan-an ni gbòǹgbò ati ọmọ Dafidi. Èmi ni ìràwọ̀ òwúrọ̀.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 22

Wo Ìfihàn 22:16 ni o tọ