Ìfihàn 3:10 BM

10 Nítorí o ti fi ìfaradà pa ọ̀rọ̀ mi mọ́, Èmi náà yóo pa ọ́ mọ́ ní àkókò ìdánwò tí ń bọ̀ wá bá ayé, nígbà tí a óo dán gbogbo àwọn tí ó ń gbé inú ayé wò.

Ka pipe ipin Ìfihàn 3

Wo Ìfihàn 3:10 ni o tọ