Ìfihàn 3:2 BM

2 Jí lójú oorun! Fún àwọn ohun tí ó ṣẹ́kù ní okun, nítorí àwọn náà ń kú lọ. Nítorí n kò rí iṣẹ́ kan tí o ṣe parí níwájú Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Ìfihàn 3

Wo Ìfihàn 3:2 ni o tọ