Ìfihàn 3:4 BM

4 Ṣugbọn o ní àwọn díẹ̀ ninu ìjọ Sadi tí wọn kò fi èérí ba aṣọ wọn jẹ́. Wọn yóo bá mi kẹ́gbẹ́ ninu aṣọ funfun nítorí wọ́n yẹ.

Ka pipe ipin Ìfihàn 3

Wo Ìfihàn 3:4 ni o tọ