Ìfihàn 4:9 BM

9 Nígbà tí àwọn ẹ̀dá alààyè mẹrin náà bá fi ògo, ọlá ati ìyìn fún ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́, ẹni tí ó wà láàyè lae ati laelae,

Ka pipe ipin Ìfihàn 4

Wo Ìfihàn 4:9 ni o tọ