Ìfihàn 6:4 BM

4 Ni ẹṣin mìíràn bá yọ jáde, òun pupa. A fi agbára fún ẹni tí ó gùn ún láti mú alaafia kúrò ní ayé, kí àwọn eniyan máa pa ara wọn. A wá fún un ní idà kan tí ó tóbi.

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:4 ni o tọ