Ìfihàn 7:4 BM

4 Mo gbọ́ iye àwọn tí a fi èdìdì sí níwájú, wọ́n jẹ́ ọ̀kẹ́ meje eniyan ó lé ẹgbaaji (144,000) láti inú gbogbo ẹ̀yà ọmọ Israẹli:

Ka pipe ipin Ìfihàn 7

Wo Ìfihàn 7:4 ni o tọ