Ìfihàn 8:11 BM

11 Orúkọ ìràwọ̀ náà ni “Igi-kíkorò.” Ó mú kí ìdámẹ́ta omi korò, ọ̀pọ̀ eniyan ni ó sì kú nítorí oró tí ó wà ninu omi.

Ka pipe ipin Ìfihàn 8

Wo Ìfihàn 8:11 ni o tọ