Ìfihàn 8:7 BM

7 Ekinni fun kàkàkí rẹ̀. Ni yìnyín ati iná pẹlu ẹ̀jẹ̀ bá tú dà sórí ilẹ̀ ayé. Ìdámẹ́ta ayé bá jóná, ati ìdámẹ́ta àwọn igi ati gbogbo koríko tútù.

Ka pipe ipin Ìfihàn 8

Wo Ìfihàn 8:7 ni o tọ