Ìfihàn 9:19 BM

19 Agbára àwọn ẹṣin wọnyi wà ní ẹnu wọn ati ní ìrù wọn. Nítorí ìrù wọn dàbí ejò, wọ́n ní orí. Òun sì ni wọ́n fi ń ṣe àwọn eniyan léṣe.

Ka pipe ipin Ìfihàn 9

Wo Ìfihàn 9:19 ni o tọ