Kọrinti Keji 1:11 BM

11 bí ẹ bá ń fi adura yín ràn wá lọ́wọ́. Nígbà náà ni ọpọlọpọ eniyan yóo ṣọpẹ́ nítorí ọpọlọpọ oore tí Ọlọrun ṣe fún wa.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1

Wo Kọrinti Keji 1:11 ni o tọ