Kọrinti Keji 1:18 BM

18 Gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti ṣe é gbẹ́kẹ̀lé, ọ̀rọ̀ wa pẹlu yín ti kúrò ní “bẹ́ẹ̀ ni” ati “bẹ́ẹ̀ kọ́.”

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1

Wo Kọrinti Keji 1:18 ni o tọ