Kọrinti Keji 1:4 BM

4 ẹni tí ó ń fún wa ní ìwúrí ninu gbogbo ìpọ́njú tí à ń rí, kí àwa náà lè fi ìwúrí fún àwọn tí ó wà ninu oríṣìíríṣìí ìpọ́njú nípa ìwúrí tí àwa fúnra wa ti níláti ọ̀dọ̀ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1

Wo Kọrinti Keji 1:4 ni o tọ