7 Ìrètí wa lórí yín sì ti fẹsẹ̀ múlẹ̀, nítorí tí a mọ̀ pé bí a ti jọ ń jẹ irú ìyà kan náà, bẹ́ẹ̀ náà ni a jọ ní irú ìwúrí kan náà.
Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1
Wo Kọrinti Keji 1:7 ni o tọ