Kọrinti Keji 10:10 BM

10 Nítorí àwọn kan ń sọ pé, “Àwọn ìwé tí Paulu kọ jinlẹ̀, wọ́n sì le, ṣugbọn bí ẹ bá rí òun alára, bí ọlọ́kùnrùn ni ó rí, ọ̀rọ̀ rẹ̀ kò sì ta eniyan lára.”

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 10

Wo Kọrinti Keji 10:10 ni o tọ