Kọrinti Keji 10:2 BM

2 Mo bẹ̀ yín, ẹ má ṣe jẹ́ kí n wá sọ́dọ̀ yín pẹlu ìgbójú, nítorí ó dá mi lójú pé mo lè ko àwọn kan, tí wọ́n sọ pé à ń hùwà bí ẹni tí ó ń wá ire ara wa lójú.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 10

Wo Kọrinti Keji 10:2 ni o tọ