Kọrinti Keji 10:8 BM

8 Nítorí ojú kò tì mí bí mo bá ń ṣe ìgbéraga ní àṣejù nípa àṣẹ tí a ní, tí Oluwa fi fún mi, láti lè mu yín dàgbà ni, kì í ṣe láti fi bì yín ṣubú.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 10

Wo Kọrinti Keji 10:8 ni o tọ