Kọrinti Keji 11:14 BM

14 Irú rẹ̀ kì í ṣe nǹkan ìjọjú, nítorí Satani pàápàá a máa farahàn bí angẹli ìmọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 11

Wo Kọrinti Keji 11:14 ni o tọ