Kọrinti Keji 11:22 BM

22 Ṣé Heberu ni wọ́n ni? Heberu ni èmi náà. Ọmọ Israẹli ni wọ́n? Bẹ́ẹ̀ ni èmi náà. Ṣé ìdílé Abrahamu ni wọ́n? Òun ni èmi náà.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 11

Wo Kọrinti Keji 11:22 ni o tọ