Kọrinti Keji 12:10 BM

10 Nítorí èyí mo ní inú dídùn ninu àìlera mi, ati ninu àwọn ìwọ̀sí, ìṣòro, inúnibíni ati ìpọ́njú tí mo ti rí nítorí ti Kristi. Nítorí nígbà tì mo bá jẹ́ aláìlera, nígbà náà ni mo di alágbára.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 12

Wo Kọrinti Keji 12:10 ni o tọ