Kọrinti Keji 13:3 BM

3 nígbà tí ó ti jẹ́ pé ẹ̀rí ni ẹ̀ ń wá pé Kristi ń lò mí láti sọ̀rọ̀. Kristi kì í ṣe aláìlera ninu ìbálò rẹ̀ pẹlu yín.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 13

Wo Kọrinti Keji 13:3 ni o tọ