Kọrinti Keji 13:9 BM

9 Nítorí náà inú wa dùn nígbà tí àwa bá jẹ́ aláìlera, tí ẹ̀yin sì jẹ́ alágbára. Èyí ni à ń gbadura fún, pé kí ẹ tún ìgbé-ayé yín ṣe.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 13

Wo Kọrinti Keji 13:9 ni o tọ