Kọrinti Keji 2:16 BM

16 Fún àwọn tí wọn ń ṣègbé, a dàbí òórùn tí n pani, ṣugbọn fún àwọn tí à ń gbàlà, a dàbí òórùn dídùn tí ó ń fún wọn ní ìyè. Ta ló tó ṣe irú iṣẹ́ yìí?

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 2

Wo Kọrinti Keji 2:16 ni o tọ