Kọrinti Keji 2:4 BM

4 Nítorí pẹlu ọpọlọpọ ìdààmú ati ọkàn wúwo ni mo fi kọ ọ́, kì í ṣe pé kí ó lè bà yín lọ́kàn jẹ́ ṣugbọn kí ẹ lè mọ̀ pé ìfẹ́ tí mo ní si yín pọ̀ pupọ.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 2

Wo Kọrinti Keji 2:4 ni o tọ