Kọrinti Keji 2:7 BM

7 Kí ẹ wá dáríjì í. Kí ẹ fún un ní ìwúrí. Bí ìbànújẹ́ bá tún pọ̀ lápọ̀jù kí ó má baà wó irú ẹni bẹ́ẹ̀ mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 2

Wo Kọrinti Keji 2:7 ni o tọ