Kọrinti Keji 2:9 BM

9 Ìdí tí mo fi kọ ìwé sí yín ni láti fi dán yín wò, kí n lè mọ̀ bí ẹ bá ń gbọ́ràn sí mi lẹ́nu ninu ohun gbogbo.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 2

Wo Kọrinti Keji 2:9 ni o tọ