Kọrinti Keji 4:11 BM

11 Nítorí pé nígbà gbogbo ni à ń fi ẹ̀mí wa wéwu nítorí Jesu, níwọ̀n ìgbà tí a wà láàyè, kí ìyè Jesu lè hàn ninu ẹran-ara wa tí yóo di òkú.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 4

Wo Kọrinti Keji 4:11 ni o tọ