Kọrinti Keji 4:13 BM

13 Àkọsílẹ̀ kan sọ pé, “Mo gbàgbọ́, nítorí náà ni mo fi sọ̀rọ̀.” Nígbà tí ó ti jẹ́ pé a ní ẹ̀mí igbagbọ kan náà, àwa náà gbàgbọ́, nítorí náà ni a fi ń sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 4

Wo Kọrinti Keji 4:13 ni o tọ