Kọrinti Keji 4:7 BM

7 Ṣugbọn bí ìkòkò amọ̀ ni àwa tí ìṣúra yìí wà ninu wa rí, kí ó lè hàn gbangba pé Ọlọrun ni ó ní agbára tí ó tóbi jùlọ, kì í ṣe àwa.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 4

Wo Kọrinti Keji 4:7 ni o tọ