Kọrinti Keji 5:1 BM

1 Nítorí a mọ̀ pé bí àgọ́ ara tí a fi ṣe ilé ní ayé yìí bá wó, a ní ilé kan lọ́dọ̀ Ọlọrun, tí a kò fi ọwọ́ kọ́, tí yóo wà lọ́run títí laelae.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 5

Wo Kọrinti Keji 5:1 ni o tọ