Kọrinti Keji 5:14 BM

14 nítorí ìfẹ́ Kristi ni ó ń darí wa, nígbà tí a ti mọ̀ pé ẹnìkan ti kú fún gbogbo eniyan, a mọ̀ pé ikú gbogbo eniyan ni ó gbà kú.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 5

Wo Kọrinti Keji 5:14 ni o tọ