Kọrinti Keji 5:16 BM

16 Àyọrísí gbogbo èyí ni pé, láti ìgbà yìí lọ, àwa kò tún ní wo ẹnikẹ́ni ní ìwò ti ẹ̀dá mọ́. Nígbà kan ìwò ti ẹ̀dá ni à ń wo Kristi, ṣugbọn a kò tún wò ó bẹ́ẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 5

Wo Kọrinti Keji 5:16 ni o tọ