6 Nítorí náà, a ní ìgboyà nígbà gbogbo. A mọ̀ pé níwọ̀n ìgbà tí a bá fi ara yìí ṣe ilé, a dàbí ẹni tí ó jáde kúrò lọ́dọ̀ Oluwa.
Ka pipe ipin Kọrinti Keji 5
Wo Kọrinti Keji 5:6 ni o tọ