Kọrinti Keji 5:9 BM

9 Nítorí èyí, kì báà jẹ́ pé a wà ninu ilé ti ibí, tabi kí á bọ́ sinu ilé ti ọ̀hún, àníyàn wa ni pé kí á sá jẹ́ ẹni ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ Oluwa.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 5

Wo Kọrinti Keji 5:9 ni o tọ