Kọrinti Keji 6:10 BM

10 A ní ìrírí ìbànújẹ́ nígbà gbogbo, sibẹ à ń yọ̀. A jẹ́ aláìní, sibẹ a ti sọ ọpọlọpọ di ọlọ́rọ̀. A dàbí àwọn tí kò ní nǹkankan, sibẹ a ní ohun gbogbo.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 6

Wo Kọrinti Keji 6:10 ni o tọ