Kọrinti Keji 6:17 BM

17 Nítorí náà ẹ jáde kúrò láàrin wọn,ẹ ya ara yín sọ́tọ̀, ni Oluwa wí.Ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́,kí n lè gbà yín.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 6

Wo Kọrinti Keji 6:17 ni o tọ