Kọrinti Keji 6:4 BM

4 Ṣugbọn ninu gbogbo nǹkan, à ń fi ara wa sípò àyẹ́sí gẹ́gẹ́ bí iranṣẹ Ọlọrun. A ti fara da ọpọlọpọ nǹkan ní àkókò inúnibíni, ninu ìdààmú, ati ninu ìṣòro;

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 6

Wo Kọrinti Keji 6:4 ni o tọ