Kọrinti Keji 7:15 BM

15 Inú Titu dùn si yín lọpọlọpọ nígbà tí ó ranti bí gbogbo yín ti múra láti ṣe ohun tí ó sọ fun yín ati bí ẹ ti gbà á pẹlu ìbẹ̀rù ati ìwárìrì.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 7

Wo Kọrinti Keji 7:15 ni o tọ