Kọrinti Keji 7:6 BM

6 Ṣugbọn Ọlọrun tí ń tu àwọn tí ọkàn wọn bá rẹ̀wẹ̀sì ninu, ti tù wá ninu nígbà tí Titu dé.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 7

Wo Kọrinti Keji 7:6 ni o tọ